Home #SelahMusic #SelahMusic: Akeju Abosede (Absolute Grace) | Omo Oba

#SelahMusic: Akeju Abosede (Absolute Grace) | Omo Oba

260
0

– New Music By Akeju Abosede (Absolute Grace) Tagged Omo Oba

Nigerian gospel music minister Akeju Abosede (Absolute Grace) continues her spirit-filled musical journey by releasing her brand new single, “Omo Oba,” off her forthcoming album.

OMO OBA is a song that’s divinely inspired and instructed by Holy Spirit, declaring the statue of God’s word towards us as the Chosen generation 1 Peter 2 vs 9 deeply rooted in the word of God Psalm 1.

Proclamation of kingdom Identity by prophesying concerning the move of divine manifestation of God’s Glory to fulfill destiny.

SEE ALSO: #SelahMusic: Uniekgrace | Involved | Feat. Ko’rale

The world has been created by Gods word, we must connect ourselves to annexing the richness of the hidden treasure on earth by declaring the word of God, aligning us to our divine purposes…

The Sound was produced by JOGM Records, with lyrics of song rearrangement and backups by the same. Studio Chouette Int did the Voicing, Mixing & Mastering.

Be sure you are going to speaking your pathways on earth to divine alignment as you listen, download, and share “Omo OBA” song.

Get Song Below

GET SONG

 

Lyrics:

Omo Oba ni mi,
Mi o kin se eru aye o
Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru satanic
Ileri ogo oluwa fun aiye mi yio wa si Imuse….
Omo oba ni mi, nwo mu ayomo mi se laye o

[Lead singer] Omo Oba ni mi,
Mi o kin se eru aye o
Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru satanic
Ileri ogo oluwa fun aiye mi yio wa si Imuse….
Eto rere olorun fun aiye mi koni ye rara o,
nwo serere, nwo tai yo, nwo di olola laye
Aki re Omo oba, ka ma ri Dansaki re
Gbogbo ibiti mo ba de laye, nwo di eni itewogba,
Nwo ko ni se aseti laye ti mo wa.
Omo oba ni mi, nwo mu ayomo mi se laye o
Chr: [Back ups] Omo Oba ni mi,
Mi o kin se eru aye o
Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru satanic
Ilori ogo oluwa fun aiye mi yio wa si Imuse….
Omo oba ni mi, nwo mu ayomo mi se laye o [Lead singer] Omo Oba ni mi,
Mi o kin se eru aye o
Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru satanic
Ileri ogo oluwa fun aiye mi yio wa si Imuse….
Eto rere olorun fun aye mi, Koni ye rara o
Oro to ba ti enu Oluwa jade koni pada si rara , kama ri Oun to ti so, dandan ko se
ibiti to ti se eto, nwo de be laye mi
Ade ogo re, Ade Wura woni, nwo de laye,
nwo de Lorun, nwo ba Jesu Joba nunu ogo tuntun… [Back ups] Omo Oba ni mi,
Mi o kin se eru aye o
Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru satanic
Ilori ogo oluwa fun aiye mi yio wa si Imuse….
Omo oba ni mi, nwo mu ayomo mi se laye o [Lead singer] Ibi mo ma de laye, dandan ni ma de be
Ite ogo ti enikeni ko Jo ko si ni iranmi
Itana ogo ti ko tan ri Lati Iran mi
Emi ni ti Iran mi reti to si ti farahan
Emi ni eni ashayan ti Oluwa ti da o
Emi ni eni ibukun, eni ogo, eni ara oto
Nwo tai yo, nwo tan, nwo lo ogo mi laye
Call: omo oba ni mi [Back ups] Omo Oba ni mi,
Mi o kin se eru aye o
Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru satanic
Ilori ogo oluwa fun aiye mi yio wa si Imuse….
Omo oba ni mi, nwo mu ayomo mi se laye o [Lead singer] Eni ba ri mi, oti ri Ola,
eni ba ri mi , oti ri eyee,
eni ba ri mi, odi alabukun fun,
oun mo ba fi owo le,
dandan ni ko se aseyori o,
Nwo tai yo , nwo se rere,
nwo di nla laye, nwo joko pelu awon oba Orilede,
Omo oba ni mi
Hun o mu ayanmo mi se o laiye o [Back ups] Omo Oba ni mi,
Mi o kin se eru aye o
Omo Oba ni mi
Mi o kin se eru satanic
Ilori ogo oluwa fun aiye mi yio wa si Imuse….
Omo oba ni mi, nwo mu ayomo mi se laye o

 

 

Connect:

Facebook: Akeju Abosede

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.