Home #SelahMusic #SelahMusicVid: Omotosho Oluwafemi | Iba | Feat. Oluwaseyi Omotosho

#SelahMusicVid: Omotosho Oluwafemi | Iba | Feat. Oluwaseyi Omotosho

16
0

– New Music By Omotosho Oluwafemi Tagged Iba 

Omotosho Oluwafemi, also known as Aksfemzy, alongside his beloved wife presents a deeply anointed new music single titled “IBA“, under the tag The Omotoshos.

Having already blessed lives with previous releases, including trending songs, Aksfemzy introduces this special project—his first collaboration with his wife.

“IBA” is a divine sound of prayer, worship, and intercession, destined to stir hearts and inspire worship.

SEE ALSO: Damilola Mike-Bamiloye Set To Feature Greatman Takit In Mount Zion Movie!

This heartfelt song is now available for download, streaming, and sharing on all digital platforms. Don’t wait—experience the power of worship today and share it with those you love.

Let this sound minister to your heart and bless you richly in Jesus’ name.

Listen & Download

https://od.lk/d/NDVfNDk0NDI1MjNf/IBA%20-%20Omotosho%20Oluwafemi%20%C3%97%20Oluwaseyi.mp3?_=1 Download

 

Lyrics:

(Instrumental opening…)

Fun Alakoso Orun, Baba ton gbe lorun
Agbe Oga e! IBA!

Fun Alakoso Aye, Baba to seda aye
Agbe Oga e! IBA!

IBA Akoda Aye, IBA
Aseda Orun, IBA
IBA Folorun loke!
IBA Akoda Aye, IBA
Aseda Orun, IBA
IBA Folorun loke!

IBA Akoda Aye, IBA
Aseda Orun, IBA
IBA Folorun loke!
IBA Akoda Aye, IBA
Aseda Orun, IBA
IBA Folorun loke!

IBA Akoda Aye, IBA
Aseda Orun, IBA
IBA Folorun loke!
IBA Akoda Aye, IBA
Aseda Orun, IBA
IBA Folorun loke!

Verse 1
Kabiyesi Olodumare!
Eni toni kokoro Aye lowo.
Oba to da Okunkun;
Oba to da Imole!

Olorun to gbe inu orun sogo,
Fun Oba to da gbogbo Aye.
Olorun to jeki Imole ko ma joba osan,
O jeki Osupa ma joba oru.

Awamaridi!
The 24 elders worship and bow before you
Because there is none to be compared to you in the heavens,
There is none to be compared to you on earth.

Olorun ti a ko ri ni, sugbon ari ese owo re.
Olorun to gbe iku mi ninu isegun.
Ohun ni Arabataribiti,
Olorun tin ngbe inu orun
To fi Aye se Apoti itise.

Oyigiyigi, IBA Fun Arugbo Ojo,
Olorun toti wa ki Aye to wa.
IBA Fun Oba to mama be nigba ti Aye ko ba si mo.

To the one who was,
To the God who is,
And the one who is to come.

Olorun ti gbogbo Aye njuba,
Ti gbogbo Aye nbo.
Olorun ti a ko ri, sugbon ari ese owo re.

Owo kembe re bi ija.
Olorun ti gbogbo Aye njuba fun.
Ohun ni Opomulero Aye,
Ohun ni Kokoro Aye,
Ohun ni Kokoro Orun.

Olorun Alagbara,
Olorun totobi ni,
Olorun toto sin ni.

Olorun ton joba Aye,
Olorun to si njoba Orun.
Oba ti aba pe nile ton je lode,
Ohun loba ti aba pe lode ton je nile.

IBA, IBA, IBA Fun Olorun awon Orun!

IBA Akoda Aye, IBA
Aseda Orun, IBA
IBA Folorun loke!
IBA Akoda Aye, IBA
Aseda Orun, IBA
IBA Folorun loke!

IBA Akoda Aye, IBA
Aseda Orun, IBA
IBA Folorun loke!
IBA Akoda Aye, IBA
Aseda Orun, IBA
IBA Folorun loke!

Verse 2

IBA Fun Olorun Shedraki,
Olorun Meshaki ati Olorun Abednigo.
We call Him the Fourth Man in the fire.
Sebi ohun ni Olorun to so ina di air-condition.

Olorun to ba iku jija kadi,
Ogba kokoro lowo iku,
Ogba Agbara lowo Isa oku.

Olorun to ni, “Iku, Oro re da?
Isa oku, Isegun re da?”

Olorun to pe Lazarus jade lati inu okuku wa.
IBA Fun Olorun to so fun Rebecca,
“That you have two nations in you.”

Oni Jacob ni mo fe ran, sugbon Isaul ni mo korira.
We call Him the Unquestionable God!
No one dares question His authority.

Olorun Owibe,
Olorun Jebe.
When He speaks, it happens.

Si olorun Babalola,
IBA Fun Olorun Adeboye,
IBA Fun Olorun emi awon Woli,
Olorun Esteri,
Si Olorun gbogbo eran ara.

Olorun to da rara;
Sebi ohun ni Olorun to da eniyan giga.
Olorun to da eniyan kukuru;
Ohun si ni Oba to da eniyan dudu.
Ohun si ni Oba to da Afin.

IBA Fun Oba to buyo ja okun Aye o,
Ara Gba Yamuyamu Okunrin Ogun.
Olorun to ngbe inu orun sogo.

Bibeli wi pe, “Ina siwaju Oluwa osi Jo awon ota re run.”
IBA Fun Olorun to fina dahun adura,
IBA Fun Olorun ton fi ina dahun gbogbo adura.

The one who fed five thousand people with five loaves of bread and two fishes.
IBA Fun Olorun to ngbe ninu Ogo.

Bibeli wi pe, “Tani o gun ori Oke Oluwa lo?
Abi tani o duro nibi mimo re?”

IBA Fun Oba to nje mimo.
IBA Fun Oba to fi mimo bora bi aso.
Kosi eni to le ba o pin ninu ogo re.

Ati Omo de, ati Agba, ati Omo inu won juba re.
Bibeli ko wi pe, “Bi eniyan ba ko lati juba re,
Oni ohun yo gbe okuta dide lati yin!”

The heavens worship Him.
The earth bows before His throne.
IBA ni gbogbo Aye nju, Olodumare!
IBA ni gbogbo Aye nju. IBA

IBA Akoda Aye, IBA
Aseda Orun, IBA
IBA Folorun loke!
IBA Akoda Aye, IBA
Aseda Orun, IBA
IBA Folorun loke!

IBA Akoda Aye, IBA
Aseda Orun, IBA
IBA Folorun loke!
IBA Akoda Aye, IBA
Aseda Orun, IBA
IBA Folorun loke!

IBA Akoda Aye, IBA
Aseda Orun, IBA
IBA Folorun loke!
IBA Akoda Aye, IBA
Aseda Orun, IBA
IBA Folorun loke!

 

Connect:

Facebook: Omotosho Oluwafemi

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.