Olabisi has finally released her single titled “Olorun Ara (God of Wonders)” produced by George Daniel.
Olabisi is a Nigerian Gospel Artiste who loves to adore the name of the Almighty God with “Ewa Ede Yoruba” (The beauty of Yoruba Language); she is a young and talented artiste, she always inspires people with her songs.
“Olorun Ara” is typically released to tell the world about the unquestionable and undefeatable wonders of God on how HE is able to destroy and build, kill and make alive, demote and enthrone kings, make a poor man dine and wine with kings, harden the heart of Pharaoh so that HIS glory could be made known and so on
Download this inspirational song, listen to it, pass to friends and loved ones.
Listen & Download
Download
Lyrics
Unquestionable
Talo je bi O lere wipe bawo lo se je?
To ba pa… O le ji
Ara lo fi da
To ba ji… O tun le pa
Ara naa nii
Kabiokosi oooo
Olusehun Ara
Alapadupe
Ara lo n da… Ara lo n da.. Ara lo da… Ara naa nii, Olusehun ara.. Alapadupe.
Vocal :O se farao laya le wipe kogo Oun le yo nii
Resp ; Ara lo n da
Vocal :O mu talaka latori atan jeun polomo alade
Resp : Ara lo N da
Vocal ;O mu oba latori ite wonu igbo lo bi eranko
Resp : Ara naa nii
Vocal : Olusehun ara Alapadupe
Olusehun ara
Alapadupe
Vocal: mo ti mo O o ni a lagbara
Mo ti mo O ni atofaratii bii oke, Talo dabi RE ninu alagbaraa laaye
Resp: Jesu mi ooo, Jesu mi
Vocal : Olusehun ara Alapadupe
Chrs : Ara lo n da /3x Ara naa nii Olusehun ara Alapadupe
Vocal : Jesu mi, oloruko aperii Ire
Jesu mi, Oba ta bi to gba kokoro lowo inu
Jesu mi onise iyanu, arogidigba ninu okun
Resp: Jesu mi ooo, Jesu mi
Vocal: Olusehun ara Alapadupe
Chrs : Ara lo n da /3x Ara naa nii Olusehun ara Alapadupe
Connect:
Twitter | Instagram: @Tianah_Olabisi




