Home #SelahMusic #SelahFresh: Elizavocat | Oruko Re

#SelahFresh: Elizavocat | Oruko Re

82
0
Elizavocat | Oruko Re

Nigeria Gospel Music Minister, Elizavocat is out with her latest new single titled “Oruko Re”

The name of the Lord is a strong tower and there is no greater power in heaven and on earth”.

“Oruko Re” is a song that affirms all things is possible when the Name of Jesus is in charge.

READ ALSO: SelahAfrik Official Top 10 Gospel Chart Of The Week | 24th – 29th May, 2021

With him we know nothing will be impossible even as we journey through the storms. His name is more than Jazz.

Listen & Download

Download

 

Lyrics:

Oh oh/2* Oruko re

Your name is more than Jazz

Oruko re jogunlo/2*

Je koruko re lana, ko lana fun mi ooo

Jekorukore lana ko Lana fun mi o

Jesu, iwo logun mi o oo

Ogun ajisa, ogun ajipe, ogun ajiyin, ogun ajibo, mope o loni ki n rowo, kire wamiri, kaye fohungbogbo toje re wamiri

Ogun ti o l’overdose , ogun ti oni prescription, ogun ti ole baje lailai, ogun ti ole womi, ogun ti ole sunko

Chorus: Je koruko re lana, ko lana fun mi ooo

Jekorukore lana kolana fun mi o

Seborukore sa nigbekele mi

Jesu, iwo logun tose gbarale, ogun ti ole dissapoint, ogun to ngbe ogun mi, ogun to bori ogun, ogun to bori epe, ogun to n woni san lorukore, ogun to n tunisile, ogun to n yoni ninu ofin,ogun to n renilekun,ogun to n ti ni leyin ogun to n pani lerin, ogun to n yaye e ni pada si rere, ogun to n saye eni dotun,ogun to n yi itan aye eni pada,ogun to n sogun dogo, ogun to n sofo dogo.

Call: Oluwa

Resp: Je koruko re lana, ko lana fun mi ooo

Jekorukore lana kolana fun mi o

Your name,

Oruko re to san bi ara, oruko re to jabi iji, oruko re lo nu omije nu, oruko re lo n taye eni se,

Oruko tokunrin npe, tobinrin npe

Tomode npe, Tagba npe, tagba npe to de n je lojojumo

Oruko to n dani nide, oruko to n wonisan, oruko to n lana fun ni, oruko to fun ni ni ireti, oruko toje jewe ategbo lo.

Chorus: Je koruko re lana, ko lana fun mi ooo

Jekorukore lana kolana fun mi o

Ogun to nje/2*

Oruko Jesu ohun nikan logun to n je

Ogun ti ole expire lailai, ogun to nje, oruko Jesu nikan logun to nje

Ogun ti ole yeye eni, ogun ti oni expire lailai, oruko Jesu nikan logun to n je

 

Connect:

Facebook: Elizavocat

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.